Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 42:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn yàrá tí ó wà ní àgbékà kẹta kò ni àwọn òpó gẹ́gẹ́ bí ilé ìdájọ́ ṣe ní; nítorí náà wọ́n kéré ni níní ààyè ju àwọn tí ó wà ní ìsàlẹ̀ àti àwọn àgbékà ti àárin.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 42

Wo Ísíkẹ́lì 42:6 ni o tọ