Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 42:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí o parí nǹkan tí ó wà nínú ilé Ọlọ́run tán, o mú mi jáde lọ sí ọ̀nà tí ó wà ní ìhà ìlà oòrùn, ó sì wọn agbégbé náà yípo:

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 42

Wo Ísíkẹ́lì 42:15 ni o tọ