Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 41:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ojú ènìyàn sí ìhà igi ọ̀pẹ ni ẹ̀gbẹ́ kan, ojú ọ̀dọ́ kìnnìún sí ìhà igi ọ̀pẹ ní ẹ̀gbẹ́ kejì. Wọn fín gbogbo rẹ̀ yípo gbogbo ilé Ọlọ́run.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 41

Wo Ísíkẹ́lì 41:19 ni o tọ