Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 40:44 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lẹ́yìn náà ó wọn àgbàlá: Ó jẹ́ ọgọ́rùn-ún ìgbọ̀nwọ́ ní gígùn, ó sì jẹ́ ọgọ́rùn-ún ìgbọ̀nwọ́ ní fífẹ. Pẹpẹ sì wà ní iwájú tẹ́ḿpìlì.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 40

Wo Ísíkẹ́lì 40:44 ni o tọ