Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 40:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àtẹ̀wọ̀ ẹnu ọ̀nà rẹ̀ tí ó dojúkọ àgbàlá tí ìta, igi ọ̀pẹ ṣe ọ̀sọ́ sí àwọn àtẹ́rígbà rẹ̀, àtẹ̀gùn mẹ́jọ ní ó lọ sì òkè sí i.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 40

Wo Ísíkẹ́lì 40:31 ni o tọ