Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 40:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn yàrá kéékèèkéé rẹ̀, àwọn ìgbéró ògiri rẹ̀ àti àtẹ̀wọ̀ ẹnu ọ̀nà jẹ́ bákan náà pẹ̀lú àwọn tí ó kù. Ẹnu ọ̀nà náà àti àtẹ̀wọ̀ ẹnu ọ̀nà rẹ̀ ní ihò ní ẹ̀gbẹ́ rẹ̀ gbogbo

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 40

Wo Ísíkẹ́lì 40:29 ni o tọ