Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 4:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Tí o bá parí èyí, tún fi ẹ̀gbẹ́ ọ̀tún dùbúlẹ̀ kí o sì ru ẹ̀ṣẹ̀ ilé Júdà fún ogójì (40) ọjọ́, nítorí pé ọjọ́ kan ló dúró fún ọdún kan.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 4

Wo Ísíkẹ́lì 4:6 ni o tọ