Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 4:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

nítorí pé oúnjẹ àti omi yóò wọ́n. Wọn yóò máa wo ara wọn pẹ̀lú ìyanu, èmi yóò sì jẹ́ kí wọ́n ṣọ̀fọ̀ nítorí ẹ̀ṣẹ̀ wọn.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 4

Wo Ísíkẹ́lì 4:17 ni o tọ