Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 39:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní orí tábìlì mi ni àwa yóò ti fi ẹṣin àti ẹlẹ́sin bọ yín yó, pẹ̀lú àwọn alágbára ńlá àti oríṣìríṣìí jagunjagun ni Olúwa Ọba sọ.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 39

Wo Ísíkẹ́lì 39:20 ni o tọ