Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 39:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi yóò dá ọ padà, èmi yóò sì darí rẹ. Èmi yóò mú ọ wá láti jìnnàjìnnà ìhà àríwá, Èmi yóò rán ọ lòdì sí orí àwọn òkè gíga Ísírẹ́lì.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 39

Wo Ísíkẹ́lì 39:2 ni o tọ