Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 38:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ àti ọ̀wọ́ ogun rẹ àti ọ̀pọ̀ orílẹ̀ èdè pẹ̀lú rẹ yóò gòkè, ẹ̀yin yóò tẹ̀ṣíwájú bí ìjì; ìwọ yóò dàbí ìkùùkuu tí ó bo ìlẹ̀ mọ́lẹ̀.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 38

Wo Ísíkẹ́lì 38:9 ni o tọ