Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 38:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣébà, Dédánì àti àwọn oníṣòwò Táṣíṣì àti gbogbo ìletò rẹ yóò sọ fún un yín pé, “Ṣé ẹ̀yin wá fún ìkógun? Ṣé ẹ̀yin ti kó àwọn ìjọ yín jọpọ̀ fún ìkógun, láti kó silífà àti wúrà lọ, láti kó nǹkan ọ̀sìn àti ẹrú àti láti gba ọ̀pọ̀ ìkógun?” ’

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 38

Wo Ísíkẹ́lì 38:13 ni o tọ