Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 37:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lẹ́yìn náà ni ó ṣọ fún mi pé, “Ṣọtẹ́lẹ̀ sí èémí; ṣọtẹ́lẹ̀, ọmọ ènìyàn, kí ó sì ṣọ fún un pé, ‘Èyí yìí ni ohun tí Olúwa àwọn ọmọ-ogun wí: wá láti atẹ́gùn mẹ́rẹ̀ẹ̀rin, ìwọ èémí, kí ó sì mí èémí sínú àwọn tí a pa wọ̀nyí, kí wọn kí ó lè wà ní ààyè.’ ”

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 37

Wo Ísíkẹ́lì 37:9 ni o tọ