Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 37:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa sì bi mí léèrè, “Ọmọ ènìyàn, ǹjẹ́ àwọn egungun wọ̀nyí lè yípadà di àwọn ènìyàn bí?”Èmi sì wí pé, “Ìwọ Olúwa àwọn ọmọ-ogun, ìwọ nìkan ni o lè dáhùn sí ìbéèrè yìí.”

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 37

Wo Ísíkẹ́lì 37:3 ni o tọ