Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 37:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣọ fún wọn pé, ‘Èyí yìí ni ohun tí Olúwa àwọn ọmọ-ogun wí: Èmi yóò gba igi Jósẹ́fù—èyí tí ó wà ní ọwọ́ Éfúráímù—àti ti ẹ̀yà Ísírẹ́lì tí ó parapọ̀ mọ́ ọn, kí ó sì só papọ̀ mọ́ igi Júdà, láti sọ wọ́n di igi kan ṣoṣo, wọn yóò sì di ọ̀kan ní ọwọ́ mi.’

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 37

Wo Ísíkẹ́lì 37:19 ni o tọ