Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 37:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lẹ́yìn náà ó ṣọ fún mi: “Ọmọ ènìyàn, àwọn egungun wọ̀nyí ni gbogbo ìdílé Ísírẹ́lì. Wọ́n ṣọ wí pé, ‘Egungun wa ti gbẹ ìrètí wa sì ti lọ; a ti gé wa kúrò.’

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 37

Wo Ísíkẹ́lì 37:11 ni o tọ