Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 36:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

nítorí náà, Ẹ̀yin òkè gíga Ísírẹ́lì gbọ́ ọ̀rọ̀ Olúwa àwọn ọmọ-ogun: Èyí yìí ní Olúwa àwọn ọmọ-ogun wí fún àwọn òkè gíga àti àwọn òkè kékèké, fún àfonífojì ńlá àti àfonífojì kékèké, fún àwọn ibi ìsọdahoro ìparun àti fún àwọn ìlú tí a ti kọ̀ sílẹ̀ tí a ti kó tí àwọn orílẹ̀ èdè tí ó kù ní àyíká sì fi ṣe ẹlẹ́yà

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 36

Wo Ísíkẹ́lì 36:4 ni o tọ