Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 36:37 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Èyí yìí ni ohun tí Olúwa àwọn ọmọ-ogun sọ: Lẹ́ẹ̀kan sí i èmi yóò yí sí ilé Ísírẹ́lì, èmi yóò sì ṣe èyí fún wọn. Èmi yóò mú kí àwọn ènìyàn yín pọ̀ lọ́pọ̀lọpọ̀ bí àgùntàn,

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 36

Wo Ísíkẹ́lì 36:37 ni o tọ