Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 36:32 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo fẹ́ kí ẹ mọ̀ pé ń kò ṣe nǹkan wọ̀nyí nítorí yín, ni Olúwa àwọn ọmọ-ogun wí. Jẹ kí ojú kí ó tì yín, kí ẹ sì gba ẹ̀tẹ́ nítorí ìwà yín ẹ̀yin ilé Ísírẹ́lì!

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 36

Wo Ísíkẹ́lì 36:32 ni o tọ