Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 36:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi yóò sì gbà yín kúrò nínú gbogbo ìwà àìmọ̀ yín. Èmi yóò pèsè ọkà, èmi yóò sì mú kí ó pọ̀ yanturu, èmi kì yóò sì mú ìyàn wá sí orí yín.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 36

Wo Ísíkẹ́lì 36:29 ni o tọ