Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 36:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi yóò wọ́n omi tó mọ́ sí yín lára ẹ̀yin yóò sì mọ́; Èmi yóò sì fọ̀ yín mọ́ kúrò nínú gbogbo ìwà èérí yin gbogbo àti kúrò nínú gbogbo òrìṣà yin.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 36

Wo Ísíkẹ́lì 36:25 ni o tọ