Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 36:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi kì yóò mú ki ó gbọ́ ọ̀rọ̀ ẹ̀gàn láti ọ̀dọ̀ àwọn orílẹ̀ èdè mọ́, ìwọ kì yóò jìyà ọ̀rọ̀ ìfiṣẹ̀sín láti ọ̀dọ̀ àwọn ènìyàn tàbí mú kí orílẹ̀ èdè rẹ ṣubú, ni Olúwa àwọn ọmọ-ogun wí.’ ”

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 36

Wo Ísíkẹ́lì 36:15 ni o tọ