Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 36:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi yóò mú kí àwọn ènìyàn, àní àwọn ènìyàn Ísírẹ́lì, rìn lórí rẹ̀. Wọn yóò gbà ọ́, ìwọ yóò sì di ogún ìní wọn; ìwọ kì yóò sì gba àwọn ọmọ wọn lọ́wọ́ wọn mọ́.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 36

Wo Ísíkẹ́lì 36:12 ni o tọ