Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 34:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ kò ì tíì mú aláìlágbára lára le tàbí wo aláìsàn sàn tàbí di ọgbẹ́ fún ẹni tí o fi ara pa. Ìwọ kò í tíì mú aṣàko padà tàbí wá ẹni tí ó nù. Ìwọ ṣe àkóso wọn ní ọ̀nà lílé pẹ̀lú ìwà òǹrorò.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 34

Wo Ísíkẹ́lì 34:4 ni o tọ