Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 34:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni wọn yóò mọ̀ pé, èmi ni Olúwa Ọlọ́run wọn, èmi wà pẹ̀lú wọn àti pé, àwọn ilé Ísírẹ́lì jẹ́ ènìyàn mi, ni Olúwa àwọn ọmọ-ogun wí.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 34

Wo Ísíkẹ́lì 34:30 ni o tọ