Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 34:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn orílẹ̀ èdè kì yóò lè kó wọn ní ẹrú mọ́, àwọn ẹranko búburú kì yóò lè pa wọn mọ́. Wọn yóò gbé ni àìléwu, kò sì sí ẹni kankan tí yóò le dẹ́rù bà wọ́n.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 34

Wo Ísíkẹ́lì 34:28 ni o tọ