Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 34:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“ ‘Èmi yóò dá májẹ̀mú àlàáfíà pẹ̀lú wọn, èmi yóò sì gba ilẹ̀ náà kúrò lọ́wọ́ ẹranko búburú, kí wọn kí o lè gbé ní aṣálẹ̀, kí àgùntàn sì gbé ní inú igbó ní àìléwu.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 34

Wo Ísíkẹ́lì 34:25 ni o tọ