Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 34:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí ti ìwọ sún síwájú pẹ̀lú ìhà àti èjìká, tí ìwọ sì kan aláìlágbára àgùntàn pẹ̀lú ìwo rẹ títí ìwọ fi lé wọn lọ,

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 34

Wo Ísíkẹ́lì 34:21 ni o tọ