Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 33:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ìrọ̀lẹ́ ọjọ́ tí ó ku ọ̀la tí ẹni tí ó sálọ náà yóò dé, ọwọ́ Olúwa sì níbẹ lára mi, o sì ya ẹnu mi ki ọkùnrin náà tó wá sọ́dọ̀ mi sílẹ̀ èmi kò sì lè dákẹ́ mọ́.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 33

Wo Ísíkẹ́lì 33:22 ni o tọ