Nítorí náà ó ga sí òkè fíofíoju gbogbo igi orí pápá lọ;Ẹ̀ka rẹ̀ pọ̀ sí i:àwọn ẹ̀ka rẹ̀ sì gùn,wọn tẹ́ rẹrẹ nítorí ọ̀pọ̀lọpọ̀ omi.