Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 3:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó tún sọ fún mi pé, “Ọmọ ènìyàn, jẹ ìwe tí mo fún ọ yìí, fi bọ́ inú àti ikùn rẹ.” Nígbà náà ni mo jẹ ẹ́, dídùn rẹ̀ dàbí oyin ní ẹnu mi.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 3

Wo Ísíkẹ́lì 3:3 ni o tọ