Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 3:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi yóò mú kí ahọ́n rẹ lẹ̀ mọ́ àjà ẹnu rẹ, tó bẹ́ẹ̀ ti ìwọ yóò wà ní ìdákẹ́ jẹ́ẹ́. Ìwọ kò sì ní lè bá wọn wí, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ọlọ̀tẹ̀ ilé ní wọn

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 3

Wo Ísíkẹ́lì 3:26 ni o tọ