Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 3:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo sì dìde mo lọ sí ibi tí ó tẹ́jú. Ògo Olúwa dúró níbẹ̀, ó dàbí irú ògo tí mo rí létí odò Kébárì, mo sì dojúbolẹ̀.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 3

Wo Ísíkẹ́lì 3:23 ni o tọ