Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 3:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí mo bá sọ fún ènìyàn búburú pé dájúdájú, ‘Ìwọ yóò kú’, tí ìwọ kò sì kìlọ̀ fún ènìyàn búburú yìí láti dáwọ́ ìwà ibi rẹ̀ dúró, kí o sì gba ẹ̀mí rẹ̀ là, ènìyàn búburú náà yóò kú nínú ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀, ṣùgbọ́n ní ọwọ́ rẹ ni èmi yóò ti béèrè ẹ̀jẹ̀ rẹ̀.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 3

Wo Ísíkẹ́lì 3:18 ni o tọ