Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 3:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Síwájú sí i, ó sọ fún mi pé, “Ọmọ ènìyàn, jẹ ohun tí ó wà níwájú rẹ, jẹ ìwé tí a ká yìí; kí o sì lọ fi bá ilé Ísírẹ́lì sọ̀rọ̀.”

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 3

Wo Ísíkẹ́lì 3:1 ni o tọ