Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 29:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí wọn fi ọwọ́ agbára wọn dì ọ́ mú. Ìwọ fọ́, ìwọ sì ya gbogbo èjìká wọn; nígbà tí wọn fi ara tì ọ́, ìwọ sẹ́, ìwọ sì mú gbogbo ẹ̀gbẹ́ wọn gbọ̀n.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 29

Wo Ísíkẹ́lì 29:7 ni o tọ