Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 29:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi yóò sọ ọ́ nù sí ihàìwọ àti gbogbo ẹja inú odò rẹ:ìwọ yóò ṣubú sí gbangba okoa kì yóò sì ṣà ọ́ jọ tàbí gbé ọ sókè.Èmi ti fi ọ ṣe oùnjẹ fún àwọn ẹranko igbóàti fún àwọn ẹyẹ ojú ọ̀run láti jẹ.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 29

Wo Ísíkẹ́lì 29:5 ni o tọ