Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 26:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Nítorí báyìí ní Olúwa Ọlọ́run wí: Kíyèsí i, láti ìhà àríwá ni èmi yóò ti mú Nebukadinésárì Ọba Bábílónì, Ọba àwọn Ọba, dide sí Tírè pẹ̀lú ẹsin àti kẹ̀kẹ́ ogun pẹ̀lú àwọn ẹlẹ́sin àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ológun.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 26

Wo Ísíkẹ́lì 26:7 ni o tọ