Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 26:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni gbogbo àwọn ọmọ aládé etíkun yóò sọ̀ kalẹ̀ láti orí ìtẹ́ wọn, wọn yóò sì pa àwọn aṣọ ìgúnwà wọn tì wọn yóò sì bọ́ àwọn ẹ̀wù wọn tí a ṣiṣẹ́ ọ̀nà sí lára kúrò. Ẹ̀rù yóò bò wọ́n, wọn yóò sì jòkòó lórí ilẹ̀ pẹ̀pẹ̀, wọn yóò sì máa wárìrì ní gbogbo ìgbà, ẹnu yóò sì yà wọ́n sí ọ́.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 26

Wo Ísíkẹ́lì 26:16 ni o tọ