Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 26:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi yóò sọ ọ di àpáta lásán, ìwọ yóò sì di ibi tí a ń sá àwọ̀n ẹja sí. A kì yóò sì tún ọ mọ nítorí èmi Olúwa ti sọ ọ̀rọ̀ ní Olúwa Ọlọ́run wí.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 26

Wo Ísíkẹ́lì 26:14 ni o tọ