Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 25:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí báyìí ni Olúwa Ọlọ́run wí: Nítorí pé ìwọ pàtẹ́wọ́, ìwọ sì jan ẹsẹ̀ mọ́lẹ̀, tí ìwọ ń yọ̀ pẹ̀lú gbogbo àrankàn rẹ sí ilẹ̀ Ísírẹ́lì

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 25

Wo Ísíkẹ́lì 25:6 ni o tọ