Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 24:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“ ‘Nítorí náà báyìí ni Olúwa Ọlọ́run wí:“ ‘Ègbé ni fún ìlú ẹlẹ́jẹ̀ náà!Èmi pàápàá yóò jẹ́ kí òkítì iná náà tóbi.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 24

Wo Ísíkẹ́lì 24:9 ni o tọ