Sì pa òwe yìí fún ilé ọlọ́tẹ̀ náà, sọ fún wọn pé: ‘Èyí yìí ni Olúwa Ọlọ́run wí:“ ‘Gbé ìkòkò ìdáná náà ka iná:Gbé e kaná kí o sì da omi sí i nínú.