Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 24:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sọ fún ilé Ísírẹ́lì, ‘Báyìí ní Olúwa Ọlọ́run wí: Kíyèsí i, èmi yóò sọ ibi mímọ́ mi di ibi àìmọ́ títayọ agbára yín, ìfẹ́ ojú yín, ìkáànú yín, àti ọmọ yín ọkùnrin àti àwọn ọmọ yín obìnrin tí ẹ̀yin fi sílẹ̀ sẹ́yìn yóò ṣubú nípa idà.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 24

Wo Ísíkẹ́lì 24:21 ni o tọ