Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 23:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èyí ẹ̀gbọ́n ń jẹ́ Óhólà, àbúrò rẹ̀ sì ń jẹ́ Óhólíbà. Tèmí ni wọn, wọ́n sì bí àwọn ọmọkùnrin àti àwọn ọmọbìnrin. Óhólà ni Samaríà, Óhólíbà sì ni Jérúsálẹ́mù.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 23

Wo Ísíkẹ́lì 23:4 ni o tọ