Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 23:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

àwọn ará Bábílónì àti gbogbo ara Kálídíà àwọn ọkùnrin Pékódùk àti Ṣóà àti Kóà àti gbogbo ará Ásíríà pẹ̀lú wọn, àwọn ọ̀dọ́mọkùnrin arẹwà, gbogbo àwọn gómìnà àti balógun, olórí oníkẹ̀kẹ́ ogun àti àwọn onípò gíga, gbogbo àwọn tí ń gun ẹṣin.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 23

Wo Ísíkẹ́lì 23:23 ni o tọ