Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 22:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìdìtẹ̀ sì wà láàrin àwọn ọmọ aládé inú rẹ̀, tó dàbí bíbú kìnnìún tó ń fà ẹ̀ran ya, wọ́n ń ba àwọn ènìyàn jẹ́, wọ́n ń kó ìsúra àti àwọn ohun iyebíye wọ́n sì ń sọ púpọ̀ di opó nínú rẹ̀.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 22

Wo Ísíkẹ́lì 22:25 ni o tọ