Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 22:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ọmọ ènìyàn, ilé Ísírẹ́lì ti di ìdárọ́ sí mi; gbogbo wọn jẹ́ bàbà, tánúnganran, ìrin àti òjé ti a fi sínú iná ìléru. Wọn jẹ́ ìdàrọ́ ti fàdákà.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 22

Wo Ísíkẹ́lì 22:18 ni o tọ