Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 22:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ǹjẹ́ ìwọ yóò lè ní ìgboyà tó, tàbí ọwọ́ rẹ yóò ni agbára ní ọjọ́ tí èmi yóò ni ṣíṣe pẹ̀lú rẹ? Èmi Olúwa ti sọ̀rọ̀, Èmi yóò sì ṣe bẹ́ẹ̀.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 22

Wo Ísíkẹ́lì 22:14 ni o tọ