Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 21:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Àti ìwọ, ọmọ ènìyàn sọ̀tẹ̀lẹ kí ó sì wí pé, ‘Èyí yìí ní ohun tí Olúwa àwọn ọmọ-ogun wí nípa àwọn ará Ámónì àti àbùkù wọn:“ ‘Idà kan idà kantí á fa yọ fún ìpànìyàntí a dán láti fi ènìyàn ṣòfòàti láti kọ bí ìmọ̀nàmọ́ná!

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 21

Wo Ísíkẹ́lì 21:28 ni o tọ